Akoran ti a ko lati ile iwosanÀkóràn tí a kó láti ilé ìwòsàn, tí a tún mò sí àkóràn nosocmial jẹ́ àkóràn tí a kó láti ilé ìwòsàn tàbí ibi ti a ti ń wo àwọn aláìsàn. [1] Ọ̀pọ̀lọpọ̀ ọ̀nà ni ènìyàn ti le kọ́ ààrùn ní ilé Ìwòsàn, ó lè jẹ́ nípa àìkíyèsí ara nígbà tí ènìyàn bá ń lo àwọn nkan èlò ilé ìwòsàn tí ààrùn ti wà lára rẹ̀ bi abéré, àwọn ọ̀be tí wón ń fi se isé abẹ́ àti àwọn ohun èlò míràn. Àìsàn tí ènìyàn bá kó ní ilé ìwòsàn má ń léwu gan nítorí pé bí ènìyàn bá lọ ògùn láti pa kòkòrò tí ó ń fà àìsàn, tí ogùn náà ò bá pa kòkòrò náà, kòkòrò yìí ó lọ tún agbára mú, èyí mú kí ògùn má le ran àwọn kòkòrò àti ilé ìwòsàn míràn nítorí wón ti gbìyànjú àti fi ọ̀gùn pá, ṣùgbọ́n kò kú, dípò ó lọ tún agbára mú ní.[2] Awọn itọkasi
|
Index:
pl ar de en es fr it arz nl ja pt ceb sv uk vi war zh ru af ast az bg zh-min-nan bn be ca cs cy da et el eo eu fa gl ko hi hr id he ka la lv lt hu mk ms min no nn ce uz kk ro simple sk sl sr sh fi ta tt th tg azb tr ur zh-yue hy my ace als am an hyw ban bjn map-bms ba be-tarask bcl bpy bar bs br cv nv eml hif fo fy ga gd gu hak ha hsb io ig ilo ia ie os is jv kn ht ku ckb ky mrj lb lij li lmo mai mg ml zh-classical mr xmf mzn cdo mn nap new ne frr oc mhr or as pa pnb ps pms nds crh qu sa sah sco sq scn si sd szl su sw tl shn te bug vec vo wa wuu yi yo diq bat-smg zu lad kbd ang smn ab roa-rup frp arc gn av ay bh bi bo bxr cbk-zam co za dag ary se pdc dv dsb myv ext fur gv gag inh ki glk gan guw xal haw rw kbp pam csb kw km kv koi kg gom ks gcr lo lbe ltg lez nia ln jbo lg mt mi tw mwl mdf mnw nqo fj nah na nds-nl nrm nov om pi pag pap pfl pcd krc kaa ksh rm rue sm sat sc trv stq nso sn cu so srn kab roa-tara tet tpi to chr tum tk tyv udm ug vep fiu-vro vls wo xh zea ty ak bm ch ny ee ff got iu ik kl mad cr pih ami pwn pnt dz rmy rn sg st tn ss ti din chy ts kcg ve